Jump to content

Micheline Calmy-Rey

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Micheline Calmy-Rey
Image
Member of the Swiss Federal Council
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
1 January 2003
AsíwájúRuth Dreifuss
President of Switzerland
In office
1 January 2007 – 31 December 2007
Vice PresidentPascal Couchepin
AsíwájúMoritz Leuenberger
Arọ́pòPascal Couchepin
Head of the Federal Department of Foreign Affairs
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
1 January 2003
AsíwájúJoseph Deiss
Vice President of Switzerland
In office
1 January 2006 – 31 December 2006
ÀàrẹMoritz Leuenberger
AsíwájúMoritz Leuenberger
Arọ́pòPascal Couchepin
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí8 Oṣù Keje 1945 (1945-07-08) (ọmọ ọdún 81)
Sion
Àwọn ọmọ2
ResidenceGeneva
{{{blank1}}}André Calmy

Micheline Anne-Marie Calmy-Rey (ọjọ́ ìbí rẹ̀ jẹ́ ọjọ́ kẹjọ oṣù kẹsàn-án 1945) jẹ́ olóṣèlú ni ìlú Switzerland tó padà di olórí fún Ẹ̀ka Ìjọba Àpapọ̀ fún Ọ̀rọ̀ òkèrè alakoso oro okere orílè-èdè Switzerland. Ó tún jẹ́ ọ̀kan lára Igbimo Ijoba Apapo Switzerland láti 2002, àti Ààrẹ ni 2007.

Calmy-Rey je bibi ni Sion ni ibile Valais fun Charles ati Adeline Rey. Calmy-Rey gba iwe eri ni 1963 ni St. Maurice, ati iwe eri DEA ninu sayensi oloselu ni Institut de hautes études internationales (HEI) (Graduate Institute of International Studies) ni 1968. O wole oko ni 1966 ni gba to fe André Calmy. Won ni omo meji.